Asoju Oba is about the search for social realism. We observe on behalf of the people. We go shout plenty!
Thursday, 29 August 2013
Apala
Mo wa n'le mo joko s'iwaju amohunmaworan bi ile ise iroyin naa ti n'da wa l'ara ya pelu awon orin ti awon osere ti se koja. Awon osere ojo oni ngbiyanju o sugbon o ye ki pupo ninu won lo ma teti si ise ti awon Baba Gani Agba Haruna Ishola ati oluku won Ayinla Omowura se seyin.
Pataki!
Pataki!
kini nkan ti o je wipe a feran ju?
se idunu ni abi owo abi omo abi ola?
Ewo ni o da ewo ni ooo da?
Subscribe to:
Comments (Atom)