Thursday, 29 August 2013

Apala

Mo wa n'le mo joko s'iwaju amohunmaworan bi ile ise iroyin naa ti n'da wa l'ara ya pelu awon orin ti awon osere ti se koja. Awon osere ojo oni ngbiyanju o sugbon o ye ki pupo ninu won lo ma teti si ise ti awon Baba Gani Agba Haruna Ishola ati oluku won Ayinla Omowura se seyin.

No comments:

Post a Comment